Published 7 months ago in Other

AGBARA IYIN - PSAM ft AMEN TIMOTHY.mp3

  • 10
  • 4
  • 0
  • 2
  • 2
  • 0

AGBARA IYIN ( power of praise) is a song by a vibrant fast rising Nigeria recording and performing gospel artist PSAM ft AMEM TIMOTHY, produce by PEEGROVES.
It's a song that gives glory to God and as well expressing how great the power of God is and how God himself empowered praise which inturn serves as an instrument of warfare


It's futher explained how people of the old like Jehosaphat, David, Paul, Silas , Peter e.t.c overcame all battles and challenges via praises to God Almighty and giving us the assurance that with PRAISE we can be victorious.

Lyrics

Chorus: Agbara Iyin
Agbara nla òun bẹ ninu ìyìn
Ìṣẹgun nla òun bẹ ninu orukọ rẹ
Iwọ lo gbo'kun wa sáré
Iwọ lo gbo'kun wa fo
Iwọ lo gbo'kun wa sáré
Iwọ lo gbo'kun wa fo
Mowárí f'agbara tóun bẹ ninu ìyìn

Verse 1: Ayérayé lo f'agbara fún ìyìn
Olusẹgun Ajasẹgun ló ro ìyìn l'agbara
Ìgbà ọ̀tá dide bi rírú omi
O gb'ọpa gún sí wọn
Ọ̀tá tíó ba le wa pa
O fi wọn ṣofo lẹyìn wa
O jẹ ká máa lá rara
Òun f'iyin wa s'ohun ìjà wa /2x


Verse 2: Oru ganjọ lo dé
Awọn èèyàn Wari
F'agbara tóun bẹ ninu ìyìn/2x
Agbára nla lo bẹ ninu ìyìn
Ìṣẹgun nla lo bẹ ninu orukọ
Iwọ lo n gbé mi sáré
Iwọ lo n gbé mi fo
Èémí rọ m'agbara tóun bẹ ninu ìyìn

Call: Iwọ lo s'eyi fún wa
Response: A mọ hàn l'ore
Call: O mu wa jẹri ọta wa
Response: A mọ hàn l'ore
Call: Ọta tíó ba le wa pa
Response : A mọ hàn l'ore
Call: Iwo lo mu jẹri wọn patapata o
Response : A mọ hàn l'ore
Call: A mọ hàn l'ore Olorun wa
Response: A mọ hàn l'ore rẹ
Call: Awọn ọta fi'ra wọn ṣofo ni Barakah
Response: A wa jagun molu , la Lai l'ẹjẹ lọ́rùn
Call: O f'isinmi fún wa l'ọtun losi, a m'ọrẹ Baba wa
Response: A mọ hàn l'ore
Call: A mọ hàn l'ore Olorun wa a mọ hàn l'ore
Bridge: Iwọ lo gbo'kun wa sáré
Iwọ lo gbo'kun wa fo
Iwọ lo gbo'kun wa sáré
Iwọ lo gbo'kun wa fo
Ẹ wa wo alagbara, ọba to rọ ìyìn l'agbara
Call: Alagbara L'ọlọrun
Vamp: Agbára 3x toun bẹ n'iyin opọ gan /2x
Adlib: Jehosafati kólé gbà gbé

00:00

there's power during worship

00:00

lord i need your power....

:
/ :

Queue

Clear