Published 2 years ago in Other

Coolprince_ft_Jemima_ft_Rosetta_-_Jesu iwo ni.mp3

  • 55
  • 1
  • 0
  • 3
  • 0
  • 0

JESU IWONI IS A SONG THAT REALLY EMPHASIS ON THE UNIQUENESS AND MYSTERY WORK OF GOD. LISTEN AND BE BLESSED.

Lyrics

Jesu iwo nikan n

Intro ....

Chorus : iwoni/3x
Jesu iwoni kan ni



Vs 1: IGI IGBO WON-TERIBA ,
Gbogbo eda nfinyin
Gbe oruko rega

GOD OF WONDERS
Alara gbayida ni


In whole wide world,,
Eyin ni kan soso nanni,

Gburagada , gbaragaada
Oba ti gbogbo aiye nsaba ni


Agbani tan baba, amoni- tan baba,
Omo oyun IGBin ninu ikarahun
Ni gbogbo ona ,
Ajewo wipe ,
iwo nikan soso -nii
Iwo ni ooo


Chorus : iwoni/3x
Jesu iwoni kan ni


Vs 2: Vs 2: Mo wonu aiye,
Kose ni to dabi re,
Baba mi, olowo gbgboro, ekun oko pharaoh.

Ogbeni nija ooo, ogbeni nija o, keru kobo nija o,
You are good , you are big and yet you are kind,
Oh, you've never failed me once,
Oh, you've never failed me once,
you are good,
always pushing me through it all
Iwo ni ooo

Chorus : iwoni/3x
Jesu iwoni kan ni

Vs 3:

Jesus the lover of my soul , ooo Jesus the owner of my life,
Through my trials and my struggles , lord you cam through for me,

When there is trouble in my life,
you are the light that I see,
In every situation,
You've always there for me,
Ohh Jesus you are my everything....


Voice : iwoni
Chorus : iwoni/3x
Jesu iwoni kan ni
Till fade out

:
/ :

Queue

Clear