Ose Pataki (Its Important) __ CitytrendTv.Com.mp3

  • 14
  • 0
  • 0
  • 4
  • 0
  • 0

Temitope praise is a vibrant gospel artist who got most of her composition through the holy Spirit and has released Nigeria@59 tagged IPA OLORUN (video), Ose pataki single, and full album tagged Gbangba(lime light). Ose pataki is a song that call every Christain to hope of eternity.

Lyrics

Chorus:
Ose Pataki
Ijoba olorun se Pataki
Ose Pataki
Ju aye ta was yi lo
Ose Pataki
Ijoba olorun se Pataki
Igba nba pari ere ije mi late
Eleduwa je n ri bi desi
Solo:
Arinrin ajo ni gbogbo eda inu aye
Bo pe bo ya a
Ao jiyin feni to ran wa nise
Ki la o po gbaye se
Ki la o pe mo gbaye se
Ose Pataki kari bi desi
Call:
Ma to ri owo ko padanu orun o
Res:
Owo atan
Call:
Ma to ri aye ko so joba orun nu
Res:
Aye a lo
Call:
Ma tori jije mimu ko so le ologo nu
Res:
Yio ti duniyan to
All:
Ose Pataki kari bi desi
Solo:
Iku Jesu ko gbodo lo lasan lori re atemi
Oji ya pupo pe kale Ba joba
Ose Pataki ka ri bi desi
Call:
Kari bi desi
Res:
Kari bi desi

:
/ :

Queue

Clear