Published 5 years ago in Other

Ebe – Sola Allyson

  • 21
  • 0
  • 0
  • 3
  • 0
  • 0

Ebe by Sola Allyson

Lyrics

Ebe Lyrics by Sola Allyson

Lord, I’ve come to seek Your face
Let Your grace and Your mercy come upon me, Lord

Oh Lord, I call upon Your name
Let the rain of Your mercy pour upon me, Lord

O oo Oluwa, mo wa sibi ite
Je ki oore ofe ati aanu Re, Oluwa
Ko ba le mi lori
Oluwa, mo ke p’Oruko Re
Je ki ojo aanu Re o, Baba
Ko ro s’ori iseda mi

Baba oo ooo, eyi l’ebe o
Baba oo ooo, eyi l’ebe o

(Baba Alaanu, Olugbebe, gbo ebe mi Oluwa o)
Baba oo ooo, eyi l’ebe o

(Aye mi ko bu ola fun O ni mo n beere)
(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)

Ona mi to wo,
ko di tito ninu ife Re Oluwa o, Eyi ni ebe mi o

Gba mi lowo asise, Oluwa o
(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)
Gba mi lowo ogun t’apa obi mi o ka,
Gba mi lowo ogun irandiran,
Oluwa gba mi oo Baba,
Iwo ni mo gbeke mi le o, Eni to ni emi mi

Oluwa too ba to mu awon afoju san,
(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)
Oba to ji oku omo Jairu dide, Oku Lasaru,
ojo merin, o ti n ra, o ti n run,
Iwo lo ji i dide o, Oluwa saanu mi

Jesu, omo Dafidi, gbo adua mi,
Oluwa
(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)
Baba oooo, Oore ofe Re ni mo beere,
aye o see gbe laisi oore ofe Re, Oluwa o

Mo fi oore ofe Re ra aye gbe, Oluwa
(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)

Atupa imo mi ko ma se ku lailai
(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)
Iwo ni opo fitila to n tan fun emi mi Oluwa ooo

Oro Re wipe bi mo beere, ma a ri gba,
mo n beere ki n ri gba
(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)
Bi mo ba kan ‘lekun,
ilekun a si, ilekun ko si, a si ti ko wipe,
bi mo ba wa kiri, ma a ri,
mo n wa kiri, ki n ri o, ki n ni ere to po, Oluwa o

Baba Alaanu ooo
(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)
Ohun gbogbo to wa ninu iseda n gbimo aanu
si ayanmo mi, won n sise iranwo lori ayanmo mi, Oluwa o

Ilekun si le, ilekun aanu si le, Oluwa
(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)
Aanu ro sori mi, o ro sori mi bee, Olugbebe gbo ebe mi o

Oh Lord I’ve come to seek Your face
Let Your grace and Your mercy come upon me, Lord
Oh Lord, I call upon Your name
Let the rain of Your mercy pour upon me, Lord
Oluwa, mo wa sibi ite
Je ki aanu ati oore ofe Re
Ko ba le mi lori
Oluwa, mo ke p’Oruko Re
Je ki ojo aanu Re
Ko ro s’ori iseda mi

Baba oo ooo, eyi l’ebe o
Baba oo ooo, eyi l’ebe o

:
/ :

Queue

Clear