Published 4 years ago in Other

IWO NIKAN by Asaph.mp3

  • 5
  • 0
  • 0
  • 0
  • 0
  • 0

Ìwọ nikan by Asaph

Lyrics

Ta léni tótó, láti shi iwe na
Taleni to ye, láti y'odidi méje yi
Ko ṣeni kan láyé lọrun níbi gbogbo
Àti ní ogbun ilé,
Af'iwo nikan.

Ojo ńlá lọ́jọ́, ta kan mogi fún ese wa
Òkú ojinde, àjíǹde iye ayeraye
Ẹni tofemire lélẹ̀ fún wa kawa leye
Kawa le bajoba
Atiye... Atiyege

Mimo mimo mimo
Mimo loluwa amin 4ce

Worthy, Worthy holy
Worthy is thy lamb amen. ..4ce

:
/ :

Queue

Clear