It's a song that is telling how unexplainable the ways of God are, and how unfathomable the depth of His faithfulness is....
Tani o le royin tan nipa Re o Oba
Ogo Re n tan Kari gbogbo aye ooooo Jesu
Ta lo le ka ise agbara Re o laye
Ami iseda n fipa agbara Re han pe O wa o
Chorus:
Baba wa orun
A yin O logo
Gba Iyin
Gba Iyin
Gba Iyin
A juba Re o Olorun wa
Kabiesi Olodumare Oba nla
Oba to n s'oun gbogbo ninu oun gbogbo
Erujeje l'eti okun pupa
Oba to n s'oun gbogbo gege bi Ife Re
Awa yin O f'eyi tO n se lowolowo yii
O se o
Ta la ba maa yin bikose Iwo
Ta la ba maa yin bikose Iwo Olorun wa
Oba to da wa si bi eniyan Re
Olorun ti o fiwa le'fe ota wa lowo, O se o
Kabiesi Baba
Oba nla to so'le aye ro
Ariiro ala Oba iyanu
Iwo nikan soso ti aiye ati orun n bo
Iwo loni Iwo lana Iwo titi aiyeraye, O se o
Mo se Kabiesi Re Baba
Olorun nla O se o
Oba awon'ba O se o
Olurapada O se
Bi'run ori je kiki ahon loni, o ha to lati yin O bi?
Sugbon Iwo to n s'oun gbogbo ninu oun gbogbo
Awa yin O a si n f'ope fun O
Fun eyi t'O n se ta si n ri lowolowo yii
O se o
O se o
Olorun wa O se o
Atobiju O se o
O se o
Chorus
Baba wa orun
A yin O logo
Gba Iyin
Gba Iyin
Gba Iyin
O se Jesu
A f'ope fun O o o o o o
Gba gbogbo Iyin o
Iwo lo l'ogo.....o o o o
O se
F'anu Re
Fun Ife Re o o
O se fun aabo Re
O se o
A dupe o
A f'ope fun O o o o o
Gba gbogbo Iyin o.......