Published 4 years ago in Other

IWO NIKAN by Asaph.mp3

  • 3
  • 0
  • 0
  • 3
  • 0
  • 0

Ìwọ nikan by Asaph

Lyrics

Taleni tótó, láti shi iwe na
Ta léni tó yẹ, láti y'edidi méje yi
Ko ṣeni kan láyé lọrun níbi gbogbo
Ati ni ogbun ile
Afiwo nikan

Ojo ńlá ta kan mogi fún ese wa
Òkú ojinde, àjíǹde iye ayeraye
Ẹni tó fẹ́mire lélẹ̀ fún wa kawa leye kawa le bajoba
Àti yẹ, atiyege

Mimo, mimo mimo
Mimo loluwa amin

Worthy worthy Holy
worthy is thy lamb amen.

:
/ :

Queue

Clear