Published 5 years ago in Other

Iranlowo - Bukola Bekes

  • 91
  • 0
  • 0
  • 10
  • 0
  • 0

Iranlowo by Bukola Bekes

Lyrics

Iranlowo Lyrics by Bukola Bekes

[Verse 1]
Emi o gbe oju mi sori oke ran ni
Ibo ni Iranlowo mi yo wa ti wa
Iranlowo mi yo to do Oluwa wa
Ti o da orun oun aye

[Chorus]
Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo

[Verse 2]
Oun ki yio je ki ese mi koye
Eniti n pamimo
Kiitogbe beeni kii sun rara o
E no dey sleep o

[Chorus]
Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo

Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo

[Chorus]
Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo
Ran mi lowo
Ran mi lowo
Ran mi lowo

:
/ :

Queue

Clear