Published 5 years ago in Other

Igba Mi Tire Ni – Sola Allyson

  • 32
  • 1
  • 0
  • 0
  • 0
  • 0

Igba Mi Tire Ni by Sola Allyson

Lyrics

Igba Mi Tire Ni Lyrics by Sola Allyson

Igba mi, tire ni (My time on earth belongs to You)
Igba mi, tire ni
Aye mi yi o ma bu ola fun O ni igba gbo gbo (My life will always give You glory)
Igba mi, tire ni

(What ever it is)
Igba mi, tire ni
(Whatever may come)
Igba mi, tire ni
Imole a ma tan si ona mi ni igba gbo gbo (Your light shines on my path always)
Igba mi, tire ni

Igba mi, tire ni
Irin ti mon rin (This journey I’m on)
Ti re ni (It is Yours)
Aye mi yi o ma bu ola fun O ni igba gbo gbo
Igba mi, tire ni

Iwo se Olododo (You are the Righteous One)
Iwo je Olododo (You are the Righteous One)
Aiye mi yi o ma be ni igba gbo gbo (My life will always say so)
Iwo je Olododo

Iwo ni alaanu (You are the Merciful One)
Alaanu l’oruko re (Merciful is Your Name)
Aiye mi yio ma fi han be ni igba gbo gbo (My life will show this always)
Alaanu l’oruko re

Mo mo o ni alaanu (I Know You as the Merciful One)
Aanu re lo gbe mi ro (It is Your mercy that kept me)
Bi o se yen tani emi (If not who Am I)
Oba to fi aanu yo mi ninu okunkun (The King whose mercy brought me out of darkness)
Ogo fun oruko re (Glory to Your Name)
Imole a ma tan si ana mi ni igba gbo gbo (Light shines on my path always)

Emi mi ti re ni (My breath is Yours)
Gbo gbo oun ti mo je ti re ni (All that I am is Yours)
Gbo gbo oun ti mo je ti re ni (All that I am is Yours)

Gbo Gbo ogo pada si odo re (All the glory returns to You)

Igba mi, tire ni
Igba mi, tire ni
Aye mi yi o ma bu ola fun O ni igba gbo gbo
Igba mi, tire ni

Wa fi mi han gege bi tire
Nipase aye mi, awon eniyan won a wa sodo re
Aiye mi yi o ma bu ola fun o ni igba gbogbo
Igba mi tire ni
I give myself to you Oluwa
I pour my all to you eni ti o ni emi mi
Aiye mi yi o maa bu ola fun ni igba gbogbo

Igba mi tire ni
Okunkun to wa lona mi, imole tan nbe
Aye mi tireni
Egun to wa lona mi, oka kuro iture wa nibe
Igba mi tire ni

I have chosen to give my life to you
Ore ofe ko ba lemi lati odo re
Gbe mi ro kin rin irin ajo yii ja, kin la ajo yi ja fun ogo re

Igba mi tire ni
Eni to ri mi, iwo ni ko ma ri Oluwa
Eni ti gbo mi ko maa gbo o ni igba gogbo
Eni ti owa si odo mi, odo re ni ki won wa Oluwa
Igba mi tire ni
Ohun ti mo nilo fifun mi Oluwa
Aiye mi tire eni
Baba mi ati Olorun mi
Igba mi tire ni

O se Olododo. ododo re ki ye
Nevertheless iwo ni Oluwa
Regardless whatever it is iwo ni Oluwa
Igba mi tire ni
Iwo ti o mumi debi wa sun mi si iwaju
Sibe sibe odo re ni mo duro si

Ko si ohun to le ya mi ya o Jesu Oluwa
Igba mi tire ni
Baba imole to tan imole si ona mi
Jesu imole mi ki o ma tan si ni igba gbogbo

Fi ara re han mi si jesu Oluwa
Igba mi tire ni
Jesu omo Olorun otito ati iye
Fi ara re han mi si
Kin se bi aye fi han ni
Imole re ko tan si ona ni ni igba gbogbo

:
/ :

Queue

Clear